Negation In Migili

NEGATION IN MIGILI

LIST OF ABBREVIATIONS AND SYMBOLS

NP              –        Noun Phrase

N                –        Noun

C                 –        Complementizer

DET            –        Determiner

S.O.V                   –        Subject, Verb, Object

P-S              –        Phrase Structure

FC              –        Focus Construction

CP              –        Complimentizer Phrase

P-M            –        Phrase Marker

TNS            –        Tense

D-S             –        Deep Structure

S-S              –        Surface Structure

Pres            –        Present

Pro              –        Pronoun

Aux            –        Auxiliary

[    ]              –        Represents Phonetic Boundary

[/]                 –        Represents High Tone

[\]                 –        Represents Low Tone

Ø                –        Null

( )                –        Brackets

VP              –        Verb Phrase

AP              –        Adjectival Phrase

PP               –        Prepositional Phrase

SPEC           –        Specifier

IP                –        Inflectional Phrase

Conj            –        Conjuction

/    /             –        Phonemic Representation

i                  –        Co-referentially

t                  –        Trace

→               –        Re-write arrow

Deg             –        Degree

Neg             –        Negation

Agr             –        Agreement

V                –        Verb

P                 –        Preposition

Adj             –        Adjective

Fig              –        Figure

                   TABLE OF CONTENT

List of Symbols and Abbreviations

Tables of Content

CHAPTER ONE

Introduction

1.0     Introduction

1.1     Historical Background of Migili People

1.2     Socio-cultural Profile of Migili

1.2.1 Religion

1.2.2 Occupation

1.2.3  Marriage and Burial rite

1.2.4 Mode of Dressing

1.2.5  Festival

1.3     Genetic Classification of Migili Language

1.4     Scope and Organisation of Migili Language

1.5     Theoretical Framework

1.6     Data Collection and Analysis

1.7     Review of Chosen Framework

1.7.1  X – Bar Theory

1.7.2   Projection Principle

1.7.3   The Head Parameter

1.7.4  Case Theory

1.7.5  Binding Theory

1.7.4  Theta (ө) Theory

1.7.5  Bounding Theory

1.7.6  Government Theory

1.7.7  Control Theory

CHAPTER TWO

Introduction to Migili Phonology And Syntax

  • Introduction

2.1    Basic Phonological Concepts

2.1.1 Vowel Sounds in Migili Language

2.1.2 Consonant Sounds in Migili Language

2.2    Tone System in Migili Language

2.3    The Syllable Structure in Migili Language

2.4    Basic Syntactic Structure Concepts

2.4.1 Phrase Structure Rule

2.4.2 Noun Phrase

2.4.3 Verb Phrase

2.4.4 Prepositional Phrase

2.4.5 Adjectival Phrase

2.5    Lexical Categories

2.5.1 Noun

2.5.1.1 Proper Nouns

2.5.1.2  Common Nouns

2.5.1.3  Abstracts Nouns

2.5.1.4  Concrete Nouns

2.5.1.5  Collective Nouns

2.5.1.6  Countable Nouns

2.5.1.7  Non Countable Nouns

2.5.2 Verbs

2.5.2.1 Transitive Verb

2.5.2.2  Intransitive Verb

2.5.3   Pronoun

2.5.4   Adjective

2.5.5   Preposition

2.5.6 Conjuction

2.5.7 Adverbs

2.5.8 Interjection

2.6    Basic Word Order in Migili Language

2.7      Sentence Types

2.7.1   Simple Sentence

2.7.2  Compound Sentence

2.7.3  Complex Sentence

2.8      Functional Classification of Sentence

2.8.1 Imperative Sentence

2.8.2  Interrogative Sentence

2.8.3  Exclamatory Sentence

CHAPTER THREE

Negation in Migili Language

  • Introduction

3.1    Negation

3.1.1 Types of Negation Formation

3.1.2 Negation of Auxiliaries

3.1.2.1 Negation of Auxiliary ‘have’, ‘do’ and ‘be’

3.1.2.2  Negation of Main Verb

3.1.3     Negation of Commands

3.2        Negation in Migili Language

3.2.1     Negation Constituents

3.2.2     Sentence Negation

3.2.3     Negation of Auxiliaries

3.2.4     Imperative Sentence Negation

3.2.5     Interrogative Sentence Negation

3.2.6     Negation of Adjectives

3.2.7     Negation of Continuous Tense

CHAPTER FOUR

Transformational Processes

4.0    Introduction

4.1    Transformations

4.1.1  Negation and Relativization

4.1.1.1 Subject NP Relativization

4.1.1.2 Object NP Relativization

4.1.2  Negation and Focus Construction

4.1.2.1 Subject NP Focusing

4.1.2.2 Direct Object NP Focusing

4.1.3    Negation and Question Formation

4.1.3.1 Yes/No Questions

4.1.3.2  WH Questions

4.1.4   Negation and Reflexivization

CHAPTER FIVE

Summary and Conclusion

5.0      Introduction

5.1      Summary

5.2      Observation

5.3      Conclusion

5.4      References

ORÍ KÌÍNÍ

ÌPILÊŚÊ IŚË ÌWÁDÌÍ

1.0   ÌFÁÀRÀ

          Kò sí àníàní pé ìlò èdè śe pàtàkì nínú iśë ônà aláwòmö lítíréśõ. Tí a bá sô pé iśë ônà lítíréśõ kan dùn, èdè inú rê ló dùn. a wá le sô pé améwìdùn, amútàndùn ni èdè, amáyédùn sì ni pêlú. Fún ìdí èyí, kì í śe àìrí-nýkan-śe bí a bá sô pé a fë śàyêwò ìlò èdè inú iśë lítíréśõ kan.

Ohun to jç wá lógún nínú iśë ìwádìí yìí ni láti śe àyêwò fínnífínni, õnà tí Olúyëmisí Adébõwálé gbà lo èdè nínú ewì Ìgbà Lonígbàákà. Èyí ni yóò ràn wá löwö láti śe ìgbéléwõn ààyè òýkõwé náà láàrín àwôn òýkõwé ewì alákôsílê Yorùbá yòókù. Bákan náà, a ò le sô ipa tí iśë òýkõwé náà le kó nínú ìdàgbàsókè ewì àpilêkô Yorùbá ní pàtàkì àti àwùjô Yorùbá lápapõ.

 1.1   ÈRÈDÍ IŚË ÌWÁDÌÍ

Yorùbá bõ wön ní êsê kan kì í dédé śe. Bí a śe mõ pé kò sí ènìyàn kan tí yóò dáwö lé iśë kan tí kò ní ní ìdí kan pàtó tí ó fi śiśë náà. Onírúurú nýkan ló mú wa lökàn tí a fi śiśë àpilêkô yìí.

Lákõökö a ti ní ìmõ lö lökàn-ò-jõkan lórí bí a śe le śe ìtúpalê iśë aláwòmö lítíréśõ kan. Fún ìdí èyí, a ní láti śàmúlò ìmõ náà nítorí pé nýkan tí a bá mõ tí a kò lò bí i pé a kò mõ ön ni.

Bákan náà ni a śe iśë yìí láti fa onírúurú àkíyèsí yô yálà àléébù tàbí ìwúlò lórí ìwé Ìgbà Lonígbàákà tí iśë yìí dálé àwôn àkíyèsí wõnyìí yóò wúlò fún wa àti fún àwùjô lápapõ. Yàtõ sí èyí, nýkan mìíràn tó tún mú wa dáwölë iśë ìwádìí yìí ni pé ìwé Ìgbà Lonígbàákà jë ìwé tuntun láwùjô, kò sí tí ì sí çnikëni tó ti śe iśë ìtúpalê ìwé náà bí i ti àwôn ìwé yókù tó jë pé ojojúmö ni àwôn onímõ lölökan-ò-jõkan ń śiśë lé wôn lórí. A wòye pé ó ye kí omi tuntun rú kí çja tuntun sí wôbê. Èyí yóò mú kí a le śàmúlò ìmõ wa nípa ìtúpalê iśë aláwòmö lítíréśõ  fínnífínní lai jë pé a wo nýkan tí àwôn onímõ ti śe lórí iśë náà. Ìdí mìíràn tí a fi śiśë yìí ni pé òýkõwé jë obìnrin iśë yìí yóò mú kí iśë àwôn obìnrin náà bêrê sí ní di ìlú mõöká.

 1.2   ÀÝFÀÀNÍ IŚË ÌWÁDÌÍ

Lákõökö iśë yìí yóò là wá lóye yóò sí tún fún wa ní ìmõ kún ìmõ nítorí ôgbön kò pín sí ibìkan bí a bá śe ń wádìí nýkan náà ni ìmõ wa yóò máa gbòró sí nítorí ôgbön kò pín síbí kan. Yàtõ sí èyí iśë yìí yóò mú ìmõ êkö têsíwàjú nítorí pé àwôn òýkõwé ti śiśë gbënàgbënà, tiwa ni láti śiśë gbënugbënu. Èyí yóò ran àwôn òýkõwé àti aśàtúpalê löwö láti ni ìmõ kún ìmõ.

Èyí nìkan kö, iśë yìí yóò fún wa ni àýfààní láti ní ìrírí lólökan ò jõkan. Èyí le wáyé yálà nígbà tí a ń śe ìwádìí lórí iśë yìí tàbí ìgbà tí a śe àkójôpõ iśë yìí. Gëgë bí a śe mõ pé lítíréśõ máa ń śàfihàn ìgbé ayé àwùjô kan ni pàápàá jùlô ìśêlê àwùjô ni ó máa ń jçyô jù nínú lítíréśõ. Iśë yìí yóò ran àwôn ènìyàn löwö láti mõ nípa àwùjô Yorùbá. A ó wò ó bóyá àyípadà ti dé bá àwùjô náà, bóyá àyípadà rere ni tàbí búburu.

Bákan náà, iśë yìí yóò fún òýkõwé ní àýfààní láti di ìlú mõká nítorí pé bí iśë bá śe ń lô lórí ìwé òýkõwé kan ni òýkõwé bëê yóò máa di gbajúmõ láwùjô. Tí a bá wo àwôn òýkõwé tó gbajú gbajà láwùjô Yorùbá, a ó rí i pé iśë ti àwôn onímõ ń śe lórí iśë wôn ló jë kó rí bëê.

Síwájú sí i, iśë yìí yóò mú kí ìwé Ìgbà Lonígbàákà dé ojú táyé, èyí pàápàá á fún wa ni ààyè láti le töka sí ibi tí àléébù bá wa nínú ìwé náà èyí yóò mú kí òýkõwé le śe àtúnśe tó báyç láti mú kí iśë mìíràn dára. Bí a bá wò ó, a ó rí i pé obìnrin ni òýkõwé ìwé yìí. Iśë yìí yóò fún àwôn obìnrin bí i tirê ní ìrírí láti le fë dàbí rê nítorí kò sí òýkõwé tí kò fë di gbajú gbajà láwùjô. Yàtõ sí èyí iśë yìí yóò ran èdè Yorùbá löwö nítorí pé àwôn ènìyàn yóò bêrê sí ní fi ojú ire wo Yorùbá àti láti nífç sí èdè Yorùbá.

Ní àkótán, iśë yìí le dúró gëgë bí àtçgùn fún àwôn tí ó ń bõ lëyìn tí ó fë śe ìwádìí lórí irú iśë yìí.

1.3   ÔGBÖN ÌWÁDÌÍ

Õpõlôpõ onímõ ló ti sõrõ nípa śíśe ìwádìí lára wôn ni Abímbölá (1995) ó pe ìwádìí ní

“Knowledge seeking that assists in adding more information to an existing compartment or content of knowledge or investigation with the soul aim of getting more knowledge, preferably new knowledge”.

Ìwádìí śíśe tí ó śe ìrànwö fún ìfikún ìmõ tàbí ìwádìí pêlú ìmõlára àti wá ìmõ kún ìmõ, pàápàá jùlô ìmõ tuntun.

Ohun tí Abímbölá ń gbìyànjú láti sô ni pé ìwádìí ni lílo ôgbön inú àti òye ikùn láti mú ohun titun jáde nípa ìmõ kan.

Onyene àti Anunnu (2000) pe ìwádìí ní:

a process of finding out solutions or answers to problems. It is  also a planning process towards seeking and getting desirable information leading to providing plausible anwer(s) to reasonable questions to enable people forecast future happenings and carry out structured investigation to solve problems.

Ìwádìí ni õnà tí à ń gbà wá õnà àbáyô tàbí ìdáhùn sí ìśòro. Òun náà ni ìlànà tí a gbé kalê fún wíwa àti rírí àwôn tí a fë tí yóò sí śokùnfà ìdáhùn sí àwôn ìbéèrè tó mögbön wá èyí yóò mú kí àwôn èèyàn le fojú inú wo àwôn ìśêlê ôjö iwájú tí wôn yóò sí śe ìwádìí tó ní ètò láti dëkun ìśòro.

Ohun tí àwôn onímõ yìí ń sô ni pé ìwádìí jë ohun tí çnìkan dáwölé tó yôrí tó sí wúlò fún ìtêsíwájú ìmõ àti fún àwùjô lápapõ. Ó jë àfikún ìmõ àti mímú ìmõ têsíwàjú bí ìwádìí tí çnìkan śe kò bá le fi kún ìmõ tó ti wà nílê tëlê, iśë jabutç ni olùwádìí bëê śe.

Yorùbá bõ wön ní ìgbà kan ò lo ilé ayé gbó, ìgbà kan ń lô, ìgbà kan ń bõ. Ní ìgbà báyému tí a wà yìí, oríśiríśi ôgbön ni a le ta láti śe ìwádìí kan tàbí òmíràn. Lára wôn ni; ìfõrõ-wáni – lënu-wò láti lô inú ôgbön ìwádìí yìí, a ni láti lô àwôn tí à ń wádìí wôn tàbí iśë wôn lô láti fi õrõ wá wôn lënu wò nítorí Yorùbá bõ wön ni çnu oníkàn la tí ń gbö põn ún. A śe èyí láti fìdí òótö múlê nípa nýkan tí a fë mõ yálà nípa òýkõwé ni tàbí nípa ìwé tí ó kô. A le śe èyí nípa lílo ìlànà ìbéèrè àti ìdáhùn. A máa ń śábà gba ohùn sílê nígbà tí a bá ń śe ìfõrõ-wáni-lënu-wò. A ti gbôdõ śètò àwôn ìbéèrè wõnyìí sílê kí a tó tô òýkõwé fún ra rê lô láti wá ìdáhùn sí àwôn ìbéèrè wa.

Síwájú sí i, a rí ôgbön ìwádìí lílo àtç tàbí àtòjô ìbéèrè (Questionaire format) èyí máa ń kún fún oríśìíríśìí ìbéèrè tí ó le ran olùwádìí löwö nínú iśë ìwádìí rê. A le pín ìwé ìbéèrè náà fún àwôn akëkõö, àwôn olùkö àwôn òśìśë ôba àti bëê bëê lô. Ìdáhùn sí àwôn ìbéèrè náà le jë bëê ni tàbí bëê kô, ó sí le jë gbólóhùn śókí. Àýfààní tó wà nínú ôgbön ìwádìí yìí ni pé ó máa ń fún olùwádìí ní àýfààní láti gba õkan-ò-jõkan ìmõ jô lórí ohun tí ó ń wádìí lé lórí, nítorí bí õrõ náà bá śe rí sí àwôn abënà-ìmõ ni wôn yóò śe dáhùn àwôn ìbéèrè tí wön bá bi wön. Ìdáhùn wôn ni yóò jë kí a mô ìhà tí wön kô sí àwôn ìbéèrè náà.

Ôgbön ìwádìí yìí kò śàì ní àléébù tirê nípa pé ó máa ń gba õpõ owó löwö olùwádìí. Èyí nìkan kö, olùwádìí le má rí àwôn àtç ìbéèrè tí ó ti pín gbà padà tán lëêkan náà tàbí kí ó má tilê rí òmíràn gbà rárá.

Ôgbön ìwádìí mìíràn tún ni èyí tí a mõ sí àśàkíyèsí akópa èyí tí ó túmõ sí pé olùwádìí yóò bá wôn kópa nínú ohun tí i ń wádìí lé lórí nípa śíśe èyí, olùwádìí yóò mô àwôn nýkan mìíràn tí ó le mõ tí ó bá śe ìfõrõ-wáni-lënu-wò lödõ àwôn abënà-ìmõ rê. Śùgbön ôgbön ìwádìí yìí le má yôrí sí rere tí àwôn abënà-ìmõ bá mõ pé ó wá śe ìwádìí ni kì í śe pé olùwádìí wá kópa lóòótö.

Ôgbön ìwádìí mìíràn ni ìwòran àśàkíyèsí. Èyí ni kí olùwádìí ó śe àmúlò èrò ìgbohùn sílê tàbí fídíò láti ká àwôn ìśêlê tí ó sílê bí wön śe ń śçlê.

Olùwádìí tún le lô sí àwôn yàrá ìkówe sí lökàn-ò-jõkan láti wá ìmõ kún ìmõ àti fún ìtösönà. Ní àkótán, ôgbön ìwádìí mìíràn ni gbígba ìmõ lórí èrò amáyélu-jára (Internet) nítorí õpõlôpõ ìmõ ni êyán le rí gbà lórí èrò náà.

Ní ti àpilêkô yìí a lo ôgbön ìwádìí ìfõrõ-wáni-lënu-wò a sì têlé ìlànà títô àwôn tí à ń wádìí iśë wôn lô láti fí õrõ wá wôn lënu wò nítorí Yorùbá bõ wön ní çnu oníkàn là á ti ń gbö põn-ún. Śíśe èyí yóò fún wa ní àýfààní láti ni ìmõ kún ìmõ lórí iśë yìí. A śe èyí láti fi ìdí òótö múlê nípa nýkan tí a fë mõ yálà nípa òýkõwé ni tàbí nípa ìwé tí ó kô. A śe èyí nípa lílo ìlànà ìbéèrè àti ìdáhùn. Àwôn ìbéèrè yìí ni mo ti śètò kí ń tó tô òýkõwé lô láti wá ìdáhùn sí àwôn ìbéèrè náà. Bákan náà mo gba ohùn sílê nígbà tí mò ń śe ìfõrõ-wáni-lënu-wò náà.

Bákan náà ni a tún lô sí yàrá ìkówésí lökan-ò-jõkan láti wá ìmõ kún ìmõ àti fún ìtösönà. Ôgbön mìíràn tí a tún lò fún iśë  ìwádìí yìí ni gbígba ìmõ lórí êrô amáyélu-jára. Ôgbön yìí wúlò púpõ fún iśë yìí nítorí ó mú kí ìmõ olùwádìí gbòòrò sí, ó jë kí òótö àbájáde ìwádìí náà túbõ fçsê múlê sí i.

1.4   ÀÀLÀ IŚË ÌWÁDÌÍ

Àwôn ewì õjõgbön Olúyëmisí Adébõwále ni iśë yìí dálé àwôn nýkan tí a sì gbé yêwò ni ônà tó gbà lo èdè tó fi mú kí iśë rê yàtõ sí ìlò èdè ojojúmö. Bákan náà a lo tíörì ìśôwö-lo-èdè láti fi èyí hàn. a mënu ba àwôn tíörì mìíràn ní śókí. Iśë yìí kò ju ìlò èdè lô àti sítàì òýkõwé tó fi gbé àwôn ìlò èdè náà jáde.

 1.5   ÈTÒ ÌWÁDÌÍ

          Iśë ìwádìí tí kò bá ní ètò kì í śe èyí tó dára nítorí pé kò ni jë kí iśë ìwádìí bëê múnádóko tó bí ó śe yç.

Orí mërin ni iśë yìí ni. Èyí rí bëê nítorí pé a kò fë kí iśë náà ó śùpõ sí ojú kan kí àwôn kókó tí a fë fà yô má baà forí mú sínú orí kan śośo.

Orí kìíní iśë yìí dá lórí ìpilêśê ìwádìí níbi tí a ti śàlàyé èrèdí iśë àpilêkô yìí. Síwájú sí i a tún fçnuba ôgbön ìwádìí èyí tó jë õnà tí a gbà láti kó àwôn èròjà ìwádìí wa jô bëê gëgë ni a mënu ba àwôn àýfààní tí ó wà nínú iśë ìwádìí èyí sí ni a fi àkòrí ìwúlò ìwádìí sí. Ètò ìwádìí lo gbêyìn orí kìíní.

Ní orí kejì, a śe àgbéyêwò iśë àwôn asíwájú èyí tí àkóónú rê dá lórí lítíréśõ Yorùbá lápapõ. A tún śàlàyé nípa tíörì ìśàmúlò èyí tí śe tíörì ìśôwö-lo-èdè.

Orí këta gan ni êmí iśë yìí nítorí pé ibè gan ni a ti śàlàyé kíkún lórí ìśôwö-lo-èdè òýkõwé ìyçn onírúurú sítàì tó wà nínú iśë rê. Bákan náà ni a sõrõ nípa àwôn çní tí a śiśë le lórí ní śókí. A sí tún sõrõ nípa Olúyçmisí Adébõwálé gëgë bí i òýkõwé àti akéwì Yorùbá.

Ní orí kërin tó gbêyìn iśë àpilêkô yìí ni a ti śe lámèyítö lórí iśë yìí. a fçnuba àmúyç àti àléébù iśë yìí. Bákan náà ni a tún sô àríwísí tiwa lórí iśë ìwádìí yìí.

Lëyìn èyí ni àgbálôgbábõ, èyí ni ìgúnlê pêlú ìmõràn fún àwôn aśèwádìí tó ń bõ lëyìn. Níparí a śe àkójôpõ orúkô àwôn ìwé tó ràn wá löwö fún iśë ìwádìí yìí.

 

 

About admin

Check Also

MALE DOMINANCE OVER THE FEMALES IN THE AFRICAN SOCIETY USING A CASE STUDY OF LOLA SHONEYIS SECRET LIVES OF BABA SEGIS WIVES AND AYOBAMI ADEBAYOS STAY WITH ME

MALE DOMINANCE OVER THE FEMALES IN THE AFRICAN SOCIETY USING A CASE STUDY OF LOLA …

IMPACT OF PIDGIN ENGLISH ON STUDENTS COMPETENCE IN FEDERAL COLLEGE OF EDUCATION ASABA

IMPACT OF PIDGIN ENGLISH ON STUDENTS COMPETENCE IN FEDERAL COLLEGE OF EDUCATION ASABA

IMPACT OF PIDGIN ENGLISH ON STUDENTS COMPETENCE IN FEDERAL COLLEGE OF EDUCATION ASABA Format: Ms …

POLITICAL SYMBOLISM AND CORRUPTION IN “BORN ON A TUESDAY” BY EL NATHAN JOHN AND “UNDER THE BROWN RUSTED ROOFS” BY ABIMBOLA ADUNNI ADELAKUN

POLITICAL SYMBOLISM AND CORRUPTION IN “BORN ON A TUESDAY” BY EL NATHAN JOHN AND “UNDER …

NEWSPAPER COVERAGE OF POLICE BRUTALITY TO CIVILIANS

NEWSPAPER COVERAGE OF POLICE BRUTALITY TO CIVILIANS Format: Ms Word Document Pages: 81 Price: N …

A PHONOLOGICAL STUDY OF ENGLISH CONSONANT DIGRAPHS IN THE UTTERANCES OF SELECTED PUPILS IN OLUYOLE LOCAL GOVERNMENT AREA

A PHONOLOGICAL STUDY OF ENGLISH CONSONANT DIGRAPHS IN THE UTTERANCES OF SELECTED PUPILS IN OLUYOLE …

SEMIOTIC STUDY OF THE SIMILARITY OF THE FRENCH AND YORUBA

A SEMIOTIC STUDY OF THE SIMILARITY OF THE FRENCH AND YORUBA

A SEMIOTIC STUDY OF THE SIMILARITY OF THE FRENCH AND YORUBA Format: Ms Word Document …

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *